‘A nílò ọdún kan láti sinmi lẹ́yìn ìbímọ’ - Òsìsẹ́ ìjọba
Published
Awọn ọmọ Naijiria ti fesi lori igbese ijọba apapọ lati fi osu kan kun ọjọ isinmi awọn osisẹ binrin to ba sẹsẹ bimọ, eleyii to sun lati osu mẹta si mẹrin.