BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Fídíò, Mo máa yẹ ìdí Seyi Makinde wò tí mo bá di gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo – Bimbo Adekanmbi, Duration 7,58
Bimbo Adekambi lo n dije du ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ oṣelu APM nipinlẹ Oyo.
Awuyewuye lórí ₦70,000 owó ìrànwọ́ tí Tinubu kéde fáwọn òṣìṣẹ́, ọ̀pọ̀ èèyàn kọminú pé ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù ọmọ Naijiria ni kò lánfààní sówó náà
Ohun ti ọpọ eeyan n sọ ni pe awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ ti yoo maa jẹ anfaani owo iranwọ N70,000 loṣooṣu yii kere ninu gbogbo ọmọ orilẹede Naijiria.
Kí ni pàtàkì Òkúta Dúdú táwọn olùjọsìn máa ń fọwọ́ kan tàbí fẹnu kò ní Kaaba lásìkò Hajj?
Lọdọọdun ni ọpọ eeyan maa n ti ara wọn, koda wọn maa n tẹ awọn mii mọlẹ nibẹ lati ri pe awọn lanfaani lati fọwọ kan okuta naa.
Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 0,54
Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́
Ẹ yẹ ìpari ìlérí Ààrẹ Tinubu láti pèsè iná wò kí ẹ tóó bú u pé kò mú àdéhùn ọdún 2023 ṣẹ-Ìjọba àpapọ̀
Ẹni ti yoo ba ṣe abosi ni yoo re ọrọ lori lai wo opin rẹ, gẹgẹ bi ileeṣẹ Aarẹ ṣe sọ
Ọkọ̀ òfúrufú já lulẹ̀, gbogbo èrò inú rẹ̀ jáde láyé
A gbọ pe agbegbe Cresthaven, to jẹ kilomita mẹrinla si Mar-a-Lago, to jẹ gbagede igbafẹ Aarẹ Donald Trump ni iṣẹlẹ naa ti waye.
Inú ebi la wà, a ń rí ẹ̀yà ara èèyàn lórí omi tí bààlúù ológun jábọ́ sí n'Igbokoda-Araalu
Yatọ si ibẹru ajakalẹ arun, awọn araalu naa ni awọn ko ri iṣẹ ṣe mọ lagbegbe ti baaluu naa jabọ si .
Àlàyé lórí ohun tó ń mú èèyàn ṣàdédé ṣubú lulẹ̀ kú láì ṣàìsàn àti ọ̀nà àbáyọ
BBC Yoruna kan si oniṣegun kan, Babalola Festus Rotimi, to jẹ dokita nile iwosan ijọba apapọ, FMC, to wa niluu Owo, nipinlẹ Ondo, lati ṣalaye ohun to maa n mu ki eeyan ṣadede ṣubu lulẹ ku.
Lẹ́yìn wákàtì díẹ̀ tí ọkọ kú nípìńlẹ̀ Ogun, ìyàwó rẹ̀ náà jáde láyé
Iṣẹlẹ yii waye lọjọ Ẹti, ọgbọnjọ oṣu Kẹwaa ọdun 2026, niluu Ikosa, Odogbolu, nipinlẹ Ogun.
Wo bí wọ́n ṣe gún àwọn ọmọdé márùn-ún níbi ayẹyẹ Halloween
Awọn ọmọ tọjọ ori wọn ko ju ọdun mẹrindinlogun si mẹtadinlogun lọ, ni awọn amookunṣeka naa gun lọbẹ, ko to di pe wọn na papa bora.
Ìyàwó àti ẹbí Toluwanisings ti fẹnu kò lórí ibi tí wọn yóò sin okú rẹ̀ sí
Akọrin ẹmi kan, Lanre Alewilese to jẹ alajọṣe pẹlu Oloogbe Toluwanisings lo kede ọrọ yii ninu fidio kan to fi soju opo Instagram rẹ.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
NCDC ṣàwári èèyàn méjì tó ṣeéṣe kí wọ́n ní àrun ebola
NCDC ti sọ pe ko tumọ si pe awọn eeyan meji ti a n sọrọ wọn yii ti ni arun naa o, amọ wọn yoo fidi ipo ti wọn wa mulẹ lẹyin ti wọn ba pari ayẹwo ti wọn n ṣe fun wọn lọwọ tan.
Wo àwọn gbankọgbì ìlérí tí àwọn olóṣèlú ti ṣe fáráàlú ní Naijiria
Lọpọ igba lawọn ileri naa maa n waye lati jẹ ki araalu dibo fun wọn, nigba mii, wọn maa n ṣe awọn ileri bẹẹ lati fi han pe wọn nifẹ araalu lọkan ju awọn alatako wọn lọ.
Olọ́pàá ṣàlàyé lórí ikú Tolufe, gbajúmọ̀ oníṣòwò tí wọ́n ló pa ara rẹ̀ l'Ondo
Ohun to n lọ kari ayelujara ni pe Tolufe pa ara rẹ ni.
Ìjọba àpapọ̀ fẹ́ máa fún àwọn ọmọ Naijiria tí ìṣẹ́ ń ṣẹ́ ní 50,000 lóṣù
Minisita fun eto iboju aanu wo ọmọniyan, Bernard Doro, ṣalaye pe say ijọba apapọ gbe eto yii kalẹ lati tete ran ọpọ ọmọ Naijiria lọwọ ni.
Ẹgbẹ́ alátakò ní Israel fẹ̀sùn kan Netanyahu lórí ètò ìdìbò tó wáyé
Ileeṣẹ eleto aabo Shin Bet ti wa sọ pe awọn ti bẹrẹ iṣẹ iwadii lati mọ boya Israel gba iranlọwọ owo lati orileede Qatar ati Turkey.
Fídíò, Níbo Layé Kọjú Sí?: Kí lobìnrin ń fẹ́ lára ọkùnrin gan? Eyiyemi Afolayan dá sí ìbéèrè yí, Duration 1,59
Eyiyẹmi ọmọ gbajumọ elere itage ni Afọlayan tọka si ifẹ ati nnkan kan, gẹgẹbi ohun ti oun n fẹ lara Ọkunrin.
Iná ṣọṣẹ́ lọ́jà Gbagi n'Ibadan, àwọn ọlọ́jà ń bèèrè ìrànlọ́wọ́ ìjọba
Ina ọhun ṣẹyọ ni nnkan bii aago meje alẹ Ọjọbọ, ọjọ kọkadinlọgbọn oṣu Kẹwaa odun 2026, ẹnikẹni ko si mọ ohun to fa a.
Àwọn jàǹdùkú ṣe ìkọlù sí Sowore ní Ekiti, òun àtàwọn èèyàn rẹ̀ farapa
Sowore ninu atẹjade kan to fi soju opo X rẹ lọjọ Ẹti fẹsun kan pe niṣe ni awọn janduku ti ijọba ipinlẹ Ekiti n ṣe atilẹyin fun lo ṣekọlu naa si oun atawọn eeyan oun ni ilu Ado Ekiti.
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ASUU, ẹ̀ka ti Lautech l'Ogbomoso bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì
Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ naa ko fi gbedeke ọjọ ti iyanṣẹlodi wọn yoo wa si opin, ṣugbọn wọn sọ pe o digba ti ijọba ba da wọn lohun, ko to di pe awọn pada sẹnu iṣẹ wọn.
Òní ni ètò ìsìnkú Michael Oyedekun, olùkọ́ tí àwọn ajínigbé gé lórí l'Oyo
Aroko ni awọn ajinigbe ọhun fi iku Oyedokun ṣe fun ijọba apapọ lọjọ naa, pẹlu bi wọn ṣe n beere fun awọn ẹtọ kan.
Kókó mẹrin ninú ẹ̀sùn ti EFCC fi kan Atiku rèé....
Iwe ẹsun naa ni Agbonayinma kọ si EFCC lati gbe ẹsun naa dide pada, to si ni ko yẹ EFCC gbagbe iru ẹsun iwa ibajẹ bẹẹ.
'Lóòótọ́ ni mò ń rówó lẹ́yìn tí mo gbìyànjú láti ṣoògùn owó àmọ́ wọ́n ní mi ò gbọdọ̀ kọ́lé tàbí ra ọkọ̀ nínú rẹ̀'
Ninu ifọrọwerọ rẹ pẹlu ile iṣẹ BBC News Yoruba niluu Ogbomoso, Pasitọ Joel ni oun ko ju bi ọmọ ogun ọdun le diẹ lọ nigba naa, eyi to jẹ nnkan bii ọgbọn ọdun sẹyin ti oun pinnu lọkan ara oun lati wu gbogbo iwa to buru julọ ki Ọlọrun le binnu si oun.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ TUC tako àdéhùn N70,000 náírà tí ìjọba àpapọ̀ ṣèlérí, wọ́n bèèrè fún àfikún owó oṣù tuntun
Nibi ipade ti awọn alakoso NLC ati ijọba ṣe lọjọ kejilelogun, oṣu yii, ni wọn ti buwọlu ẹgbẹrun lọna aadọrin naira gẹgẹ bi owo iranwọ ọkọ wiwọ fun awọn oṣiṣẹ.
Ọkọ reluwé méjì kọlu ara wọn, èèyàn 68 kú, ìjọba kéde ọ̀fọ̀ ọjọ́ mẹ́ta
Aarọ Ọjọru, ọsẹ yii ni ijamba naa waye, nigba ti wọn sọ pe reluwee ti ileeṣẹ aladani kan ti wọn pe ni Iryo to n bọ lati ilu Madrid lọ si Seville lọ kọlu reluwee to jẹ ti ijọba.
Òní Ọjọ́bọ ni Adebutu,Pantami àtàwọn yòókù tí INEC yọ orúkọ wọn yóò mọ ohun tó kàn
Kọmiṣanna apapọ fun ajọ INEC, Mohammed Haruna, lo fidi ẹ mulẹ pe awọn eeyan naa yoo mọ bo ṣe n lọ lonii.
Ààrẹ Tinubu dágbére Makkah fọ́mọ Nàíjíríà
Onanuga sọ pe Ọjọbọ, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu Kẹwaa, ni Aarẹ Tinubu yoo gbera lati papakọ ofurufu Nnamdi Azikiwe to wa niluu Abuja.
'Nítorí pé èèyàn kan fi mí we ọ̀bọ ló jẹ́ kí n lọ bóra'
O ni lasiko igba naa, awọn eeyan to ba pupa ni wọn maa n pe si iṣẹ eyi to mu oun naa pinnu lati lọ bora ki oun naa le maa ri iṣẹ gba.
INEC lóun yóò wádìí àwòrán àwọn olùdìbò táwọn ọmọ Naijiria sọ pé AI ni lójú òpó rẹ̀
Bakan naa lawọn eeyan kan tun tọka pe awọn orukọ kan ko si ninu eyi ti INEC gbe jade, bẹẹ lawọn kan sọ pe ẹẹmeji lo gbe orukọ awọn jade.
Ka ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ọ̀dọ́kùnrin Zamfara tó pè fún pípa àwọn Kristẹni
Afurasi to lewaju ninu fidio naa ni orukọ rẹ n jẹ Umar Ibrahim Gandi Maradun.
Fídíò, Wọ́n máa ń nà mí tí mo bá lọ gbá bọ́ọ̀lù láì kiri ẹja àmọ́ lónìí, mo di ìlúmọ̀ọ́ká agbọ́bọ́ọ̀lù - Suliat Abideen, Duration 2,25
BBC News Yoruba ba gbajumọ elere bọọlu lobinrin, Sulia Abideen sọrọ, o salaye idi to se yan isẹ bọọlu gbigba laayo ati bi igba ewe rẹ se ri.
Kí ló dé tí DSS ṣe mú alátìlẹ́yìn Atiku, fojú rẹ̀ ba ilé ẹjọ́?
Iwaju ileẹjọ Majisireti to w ani ojule Kẹwa, opopona Kabala Doki, nipinlẹ Kaduna, ni DSS wọ ọkunrin naa lọ, ti adajọ si pasẹ pe ki wọn fi si ọgba ẹwọn ilu Kaduna.











































































