Passport Nàìjírìa: Gbèdéke ọdún mẹ́wàá ti wà fún páálí ìrìnnà Nàìjírìa

Àkọlé fídíò, Passport Nàìjírìa: ìjọba ti sọ gbèdéke ori ìwé ìrìnnà di ọdun mẹ́wàá
Published

Idunnun ṣubu layọ fun awọn ọmọ Naijiria bi ijọba apapọ ti sọ iwe irinna di ọdun mẹwaa lati ọdun marun un ti o wa tẹlẹ ki o to di pipaarọ.

Awọn eeyan to ba BBC Yoruba sọrọ ni ofisi iwe irinna ni Ikoyi nipinlẹ Eko kan saara si igbẹsẹ ijọba naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: